Tue Jun 15 2021 10:35:48 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-06-15 10:35:49 +01:00
parent e0f57d81a8
commit dbfab3051b
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Ẹ̀yin ìyàwó, ẹ tẹríba fún àwọn ọkọ yín, gẹ́gẹ́ bí ó ti tọ́ nínú Olúwa. \v 19 Ẹ̀yin ọkọ, ẹ fẹ́ràn àwọn ìyàwó yín, kí ẹ má sì ṣe korò sí wọn. \v 20 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ràn si àwọn òbí yín lẹ́nu nínú ohun gbogbo, nítorí eyí ní o dára nínú Olúwa. \v 21 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má se máa mu àwọn ọmọ yín bínú, kí wọn má bá rẹ̀wẹ̀sì.
\v 18 Ẹ̀yin ìyàwó, ẹ tẹríba fún àwọn ọkọ yín, gẹ́gẹ́ bí ó ti tọ́ nínú Olúwa. \v 19 Ẹ̀yin ọkọ, ẹ fẹ́ràn àwọn ìyàwó yín, kí ẹ má sì ṣe korò sí wọn. \v 20 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ràn sí àwọn òbí yín lẹ́nu nínú ohun gbogbo, nítorí èyí ni ó dára nínú Olúwa. \v 21 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má ṣe mú àwọn ọmọ yín bínú, kí wọ́n má baà rẹ̀wẹ̀sì.

View File

@ -1 +1 @@
\v 22 Ẹ̀yin ẹrú, e máa gbọ́ràn sí àwọn olówó yín níti ara lẹ́nu nínú ohun gbógbó, ki se pẹ̀lú ojú-aye, bi awọn ti nfẹ́ lati tẹ̀ ènìyàn lọ́rùn, sùgbọ́n pẹ̀lu ọkàn tí ó tọ́. Ẹ bẹ̀ru Ọlọrun. \v 23 Ohunkóhun ti ẹ bá nsé, ẹ siṣẹ́ láti inú ọkàn gẹ́gẹ́bí fún Olúwa ti kìí si se fún àwọn ènìyàn \v 24 Ẹ̀yín mọ pé ẹ ó gba èrè ogún ìbí láti ọ̀dọ̀ Olúwa. Kristi Olúwa ní ẹ̀yín nsìn. \v 25 Nítorí ẹnikẹ́ni ti ó bá ṣe àisòdodo yio gba èrè fún àisododo ti o ṣe, àti pé kò sí ojúsàájú.
\v 22 Ẹ̀yin ẹrú, máa gbọ́ràn sí àwọn olówó yín níti ara lẹ́nu nínú ohun gbógbó, ki se pẹ̀lú ojú-aye, bi awọn ti nfẹ́ lati tẹ̀ ènìyàn lọ́rùn, sùgbọ́n pẹ̀lu ọkàn tí ó tọ́. Ẹ bẹ̀ru Ọlọrun. \v 23 Ohunkóhun ti ẹ bá nsé, ẹ siṣẹ́ láti inú ọkàn gẹ́gẹ́bí fún Olúwa ti kìí si se fún àwọn ènìyàn \v 24 Ẹ̀yín mọ pé ẹ ó gba èrè ogún ìbí láti ọ̀dọ̀ Olúwa. Kristi Olúwa ní ẹ̀yín nsìn. \v 25 Nítorí ẹnikẹ́ni ti ó bá ṣe àisòdodo yio gba èrè fún àisododo ti o ṣe, àti pé kò sí ojúsàájú.

View File

@ -65,7 +65,7 @@
"03-09",
"03-12",
"03-15",
"03-22",
"03-18",
"04-title",
"04-01",
"04-02",