Sat Jun 12 2021 20:11:18 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-06-12 20:11:18 +01:00
parent c09d842f6f
commit b9cab0e684
3 changed files with 3 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 4 Àwá ti gbọ́ nípa ìgbàgbó yín nínú Krístì Jésù àti nípa ti ìfẹ́ tí ẹ̀yín ní sí gbogbo àwọn ènìyaǹ mímọ́ O̩ló̩run. \v 5 Ìfẹ́ yìí ni ẹ̀yín ní nítorí ìrètí tí ó wà ní ìpamọ́ fún yín ní ọ̀run. Ẹ̀yin ti kọ́kọ́ gbọ́ sáájú nípa ìrètí yìí nínú ọ̀rọ̀ òtítọ́, àní ìyìnrere, \v 6 èyítí ó tọ̀ yín wá. Ììnrere yìí ń so èso bẹ́ẹ̀ni ó sì ń gbilẹ̀ si ní gbogbo àgbáyé. Bákanńà ni ó sì ń dàgbà nínú yín pẹ̀lú láti ọjọ́ tí ẹ ti gbọ́ tí ẹ sì ti kọ́ nípa oore-ọ̀fẹ́ O̩ló̩run nínú òtítọ́.
\v 4 Àwá ti gbọ́ nípa ìgbàgbó yín nínú Krístì Jésù àti nípa ti ìfẹ́ tí ẹ̀yín ní sí gbogbo àwọn ènìyaǹ mímọ́ O̩ló̩run. \v 5 Ìfẹ́ yìí ni ẹ̀yín ní nítorí ìrètí tí ó wà ní ìpamọ́ fún yín ní ọ̀run. Ẹ̀yin ti kọ́kọ́ gbọ́ sáájú nípa ìrètí yìí nínú ọ̀rọ̀ òtítọ́, àní ìyìnrere, \v 6 èyítí ó tọ̀ yín wá. Ìyìnrere yìí ń so èso bẹ́ẹ̀ni ó sì ń gbilẹ̀ si ní gbogbo àgbáyé. Bákanńà ni ó sì ń dàgbà nínú yín pẹ̀lú láti ọjọ́ tí ẹ ti gbọ́ tí ẹ sì ti kọ́ nípa oore-ọ̀fẹ́ O̩ló̩run nínú òtítọ́.

View File

@ -1 +1 @@
\v 24 Nísinsìnyí èmi nyọ̀ nínú àwọn ìjìyà mí fuń yín, àti pé èmí fi aramọ ìjìya Kristi ti o kù nítorí ara rè, eléyìí tí se ìjọ̀. \v 25 Nítorí ti ìjọ ni èmí se jẹ́ ìránṣẹ́, gẹ́gẹ́bí òjúṣe tí a fi fún mi sí yín láti ọ̀dọ Ọlọrun wa, láti mú ọ̀rọ̀ Ọlọrun ṣẹ. \v 26 Èyii ni ohun ìjìnlẹ̀ ti a ti pamọ́ láti aiyéraiyé ati latí ìrandíran, sugbọn niṣinṣinyii ati fihàn fún àwọ̀n ènìyàn mímọ́ Ọlọrun. \v 27 Àwọn ní Ọlọrun ti nfẹ láti fi ìjìnlẹ ọrọ̀ ogo Rẹ̀ han fún làárin awọn kèfèrí, eleyii ti se Kristi nínú yín, ìrètí ògo.
\v 24 Nísinsìnyí èmi ń yọ̀ nínú àwọn ìjìyà mi fún yín, àti pé èmi fi ara mọ́ ìjìya Kristi ti o kù nítorí ara rè, eléyìí tí se ìjọ̀. \v 25 Nítorí ti ìjọ ni èmí se jẹ́ ìránṣẹ́, gẹ́gẹ́bí òjúṣe tí a fi fún mi sí yín láti ọ̀dọ Ọlọrun wa, láti mú ọ̀rọ̀ Ọlọrun ṣẹ. \v 26 Èyii ni ohun ìjìnlẹ̀ ti a ti pamọ́ láti aiyéraiyé ati latí ìrandíran, sugbọn niṣinṣinyii ati fihàn fún àwọ̀n ènìyàn mímọ́ Ọlọrun. \v 27 Àwọn ní Ọlọrun ti nfẹ láti fi ìjìnlẹ ọrọ̀ ogo Rẹ̀ han fún làárin awọn kèfèrí, eleyii ti se Kristi nínú yín, ìrètí ògo.

View File

@ -39,6 +39,7 @@
"finished_chunks": [
"front-title",
"01-01",
"01-04",
"01-07",
"01-09",
"01-11",