Sun Jun 13 2021 13:00:50 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-06-13 13:00:51 +01:00
parent 82425a065d
commit b5f59ab536
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\c 2 \v 1 Nítorí èmí fẹ́ kí ẹ̀yin mọ ìjàkadì tí èmi ní fún yín, fún àwọn tó wà ní Laodíkìa, àti fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wọn kò'tíì rí mi lójúkojú. \v 2 Mo tiraka kí á ba lè mú wọn lọ́kàn le nípa mímú wọn parapọ̀ nínú ìfẹ́ àti sínú gbogbo ọrọ̀ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ òye Rẹ̀ tó dájú, sínú ìmọ̀ àṣírí ìjìnlẹ̀ Ọlọrun, àní Kristri. \v 3 Nínú ẹnití a fi gbobgo ìsúra ọgbọn àti ìmọ̀ pamọ́ sí. \c 2 \v 1 Nítorí èmí fẹ́ kí ẹ̀yin mọ ìjàkadì tí mo ní fún yín, fún àwọn tó wà ní Laodíkìa, àti fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wọn kò tíì rí mi lójúkojú. \v 2 Mo tiraka kí á ba lè mú wọn lọ́kàn le nípa mímú wọn parapọ̀ nínú ìfẹ́ àti sínú gbogbo ọrọ̀ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ òye Rẹ̀ tó dájú, sínú ìmọ̀ àṣírí ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run, àní Krístì. \v 3 Nínú ẹnití a fi gbobgo ìsúra ọgbọn àti ìmọ̀ pamọ́ sí.

View File

@ -1 +1 @@
\v 4 Mo sọ eyii kí ẹnikẹ́ni maa ba fi ọ̀rọ̀ dídùn tàn yín jẹ. \v 5 Lotitọ èmi ko sí pẹ̀lu yín lójúkoojú, sibẹ́ èmí wa pẹ̀lu yín nínú ẹ̀mí. Mo yọ láti mọ èto yín àti ìdúroṣinṣin yín nínú Kristi. \v 4 Mo sọ èyí kí ẹnikẹ́ni má baà fi ọ̀rọ̀ dídùn tàn yín jẹ. \v 5 Lotitọ èmi ko sí pẹ̀lu yín lójúkoojú, sibẹ́ èmí wa pẹ̀lu yín nínú ẹ̀mí. Mo yọ láti mọ èto yín àti ìdúroṣinṣin yín nínú Kristi.

View File

@ -50,7 +50,7 @@
"01-24", "01-24",
"01-28", "01-28",
"02-title", "02-title",
"02-04", "02-01",
"02-06", "02-06",
"02-08", "02-08",
"02-10", "02-10",