Thu May 27 2021 14:02:36 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-05-27 14:02:42 +01:00
parent 5a51d5ebc7
commit a49bc6064b
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Ẹ máa se purọ́ fún ara yín, nígbàtí ó jẹ́ wípé ẹ̀yín ti bọ ọkùnrin àtijọ́ nì sílẹ̀ àti àwọn ìse rẹ̀. \v 10 ẹ̀yín sì ti gbé ọkúnrin titun ni wọ̀, ẹnití a se ní ọ̀tun ni ìmọ̀ gẹ́gẹ́bí àwòrán enití o dáa \v 11 Ní ibìyí ni kò ti sí pé eleyìí ni Gírìkì tàbí Júú, ẹnití ó kọlà ati ẹnití kò kọlá, aláìgbédè, ara Skitia, ẹrú, ònìnira, sùgbọn Kristi ni ohun gbogbo, O sì wà nínú ohun gbogbo.
\v 9 Ẹ máa se purọ́ fún ara yín, nígbàtí ó jẹ́ wípé ẹ̀yín ti bọ ọkùnrin àtijọ́ nì sílẹ̀ àti àwọn ìse rẹ̀. \v 10 ẹ̀yín sì ti gbé ọkúnrin titun ni wọ̀, ẹnití a se ní ọ̀tun ni ìmọ̀ gẹ́gẹ́bí àwòrán enití o dáa \v 11 Ní ibìyí ni kò ti sí pé eleyìí ni Gírìkì tàbí Júú, ẹnití ó kọlà ati ẹnití kò kọlá, aláìgbédè, ara Síkitia, ẹrú, ònìnira, sùgbọn Kristi ni ohun gbogbo, O sì wà nínú ohun gbogbo.

View File

@ -1 +1 @@
\v 12 Nítorína, gẹ́gẹ́bi àwọn ti Ọlọrun ti yàn, mímọ́ àti àyànfẹ́, ẹ gb´ ọkàn àánú wọ̀, ìsore, ìrẹ̀lẹ̀, inú tútu àti sùúrù. \v 13 Ki ẹ máa farada fún ara yín. Ẹ máa yọ́nú si ara yín. Bi ẹnìkan ba ní ẹ̀sùn si ẹlòmíràn, ẹ máa dáríjì ní ọ̀nà kannáà ti Olúwa ti dáríjì yín \v 14 Borí gbogbo nkan wọ̀nyi, ẹ ní ìfẹ́, eléyìí ti se àmùré ìwà pípé.
\v 12 Nítorína, gẹ́gẹ́bi àwọn ti Ọlọrun ti yàn, mímọ́ àti àyànfẹ́, ẹ gbé ọkàn àánú wọ̀, ìsore, ìrẹ̀lẹ̀, inú tútu àti sùúrù. \v 13 Ki ẹ máa farada fún ara yín. Ẹ máa yọ́nú si ara yín. Bi ẹnìkan ba ní ẹ̀sùn si ẹlòmíràn, ẹ máa dáríjì ní ọ̀nà kannáà ti Olúwa ti dáríjì yín \v 14 Borí gbogbo nkan wọ̀nyi, ẹ ní ìfẹ́, eléyìí ti se àmùré ìwà pípé.