Sat Jun 12 2021 19:37:17 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
e4f051ecc1
commit
9fde4e0a7b
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 18 Òun ni orí fún ara, àní fún ìjọ. Òun ni ìpilẹ̀sẹ̀ àti àkóbí nínú àwọn òkú, nítorínà ni Ó ṣe ní ipò ìṣaájú nínú ohun gbogbo. \v 19 Nítorí ó wu Ọlọ́run pé kí ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Òun maa gbé inú rẹ̀, \v 20 àti láti se ìbálàjà ohun gbogbo fún ara Rẹ̀ nípasẹ̀ ọmọ. Ọlọrun se ètò àláfìa nípasẹ ẹ̀jẹ rè lórí igi àgbélébǔ. Ọlọrun ra ohun gbogbo pada fún ara Rẹ̀, yala àwọn ohun ti nbẹ ni aiyé tàbí àwọn ohun ti nbẹ ni ọ̀run.
|
||||
\v 18 Òun ni orí fún ara, àní fún ìjọ. Òun ni ìpilẹ̀sẹ̀ àti àkóbí nínú àwọn òkú, nítorínà ni Ó ṣe ní ipò ìṣaájú nínú ohun gbogbo. \v 19 Nítorí ó wu Ọlọ́run pé kí ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Òun máa gbé inú Rẹ̀, \v 20 àti láti ṣe ìbálàjà ohun gbogbo sọ́dọ̀ ara Rẹ̀ nípasẹ̀ Ọmọ. Ọlọ́run ṣe ètò àláfìa nípasẹ ẹ̀jẹ rè lórí igi àgbélébǔ. Ọlọrun ra ohun gbogbo pada fún ara Rẹ̀, yala àwọn ohun ti nbẹ ni aiyé tàbí àwọn ohun ti nbẹ ni ọ̀run.
|
Loading…
Reference in New Issue