Sat Jun 12 2021 18:59:17 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-06-12 18:59:18 +01:00
parent 07c2b8ca2b
commit 8b2358348e
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Nítorí ìfẹ́ yìí, àwa ko dáwọ́ àdúrà dúró lórí yín. Àwa sí ti ń béèrè pé kí á fi ìmọ̀ ìfẹ́ Rẹ̀ kún yín nínú gbogbo ọgbọ́n àti òye ohun Ẹ̀mí \v 10 Àwá sí tí ń gbàdúrà pe kí ẹ̀yín kio le rìn ni pípé nínu àwọn ọ̀nà tí mú inú Ọlọrun dùn. Àwá ntí gbàdúrà pé kí ẹ̀yin so èso rere nínú gbogbo iṣẹ́ rere yín ati pẹ̀lúpẹ̀lú kí ẹ̀yín dàgbà nínú ìmọ Ọlọrun.
\v 9 Nítorí ìfẹ́ yìí, àwa ko dáwọ́ àdúrà dúró lórí yín. Àwa sí ti ń béèrè pé kí á fi ìmọ̀ ìfẹ́ Rẹ̀ kún yín nínú gbogbo ọgbọ́n àti òye ohun Ẹ̀mí \v 10 Àwá sí tí ń gbàdúrà pe kí ẹ̀yín kí ó lè rìn ní pípé nínú àwọn ọ̀nà tí ó mú inú Ọlọ́run dùn. Àwá ntí gbàdúrà pé kí ẹ̀yin so èso rere nínú gbogbo iṣẹ́ rere yín ati pẹ̀lúpẹ̀lú kí ẹ̀yín dàgbà nínú ìmọ Ọlọrun.