From 80cd26ac4db7af140d16b3597fbbf6ef252d6fde Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Sat, 12 Jun 2021 19:33:18 +0100 Subject: [PATCH] Sat Jun 12 2021 19:33:17 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 01/18.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/01/18.txt b/01/18.txt index 9fff7d7..cbfc02e 100644 --- a/01/18.txt +++ b/01/18.txt @@ -1 +1 @@ -\v 18 Òun ni orí fún ara, àní fún ìjọ. On ni ìpilẹ̀sẹ̀ ati àkóbí nínú àwọn òkú, nítorínà ni ó se ní ipo tí ó dára jùlọ nínú ohun gbogbo. \v 19 Nítorí tí inu Ọlọrun dún pe ki ẹ̀kuńrẹ́rẹ́ Òún maa gbé inú rẹ̀, \v 20 àti láti se ìbálàjà ohun gbogbo fún ara Rẹ̀ nípasẹ̀ ọmọ. Ọlọrun se ètò àláfìa nípasẹ ẹ̀jẹ rè lórí igi àgbélébǔ. Ọlọrun ra ohun gbogbo pada fún ara Rẹ̀, yala àwọn ohun ti nbẹ ni aiyé tàbí àwọn ohun ti nbẹ ni ọ̀run. \ No newline at end of file +\v 18 Òun ni orí fún ara, àní fún ìjọ. Òun ni ìpilẹ̀sẹ̀ àti àkóbí nínú àwọn òkú, nítorínà ni Ó ṣe ní ipò tí ó dára jùlọ nínú ohun gbogbo. \v 19 Nítorí tí inu Ọlọrun dún pe ki ẹ̀kuńrẹ́rẹ́ Òún maa gbé inú rẹ̀, \v 20 àti láti se ìbálàjà ohun gbogbo fún ara Rẹ̀ nípasẹ̀ ọmọ. Ọlọrun se ètò àláfìa nípasẹ ẹ̀jẹ rè lórí igi àgbélébǔ. Ọlọrun ra ohun gbogbo pada fún ara Rẹ̀, yala àwọn ohun ti nbẹ ni aiyé tàbí àwọn ohun ti nbẹ ni ọ̀run. \ No newline at end of file