Tue Jun 15 2021 09:43:48 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-06-15 09:43:52 +01:00
parent 19532601f8
commit 2f3936fbb1
2 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\c 3 \v 1 Bí ó bá jẹ́ wípé Ọlọ́run ti jí yín pẹ̀lú Krístì, ẹ sàfẹẹ́rí àwọn nǹkan tí ń bẹ lókè, níbití Krístì gbé jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún Ọlọ́run. \v 2 Ẹ ronú nípa àwọn nǹkan tí ń bẹ lókè, kìí ṣe àwọn nǹkan tí ń bẹ ní ayé. \v 3 Nítorítí ẹ ti kú, a sì ti fi ẹ̀mí yín pamọ́ pẹ̀lú Krístì nínú Ọlọ́run. \v 4 Nígbàtí Krístì bá fi ara hàn, ẹnití Í ṣe ayé yín, nígbànáà ni eyin náà yio farahàn pẹ̀lu rẹ̀ nínú ògo.
\c 3 \v 1 Bí ó bá jẹ́ wípé Ọlọ́run ti jí yín pẹ̀lú Krístì, ẹ sàfẹẹ́rí àwọn nǹkan tí ń bẹ lókè, níbití Krístì gbé jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún Ọlọ́run. \v 2 Ẹ ronú nípa àwọn nǹkan tí ń bẹ lókè, kìí ṣe àwọn nǹkan tí ń bẹ ní ayé. \v 3 Nítorítí ẹ ti kú, a sì ti fi ẹ̀mí yín pamọ́ pẹ̀lú Krístì nínú Ọlọ́run. \v 4 Nígbàtí Krístì bá fi ara hàn, ẹnití Í ṣe ìyè yín, nígbànáà ni ẹ̀yin náà yó farahàn pẹ̀lú Rẹ̀ nínú ògo.

View File

@ -60,6 +60,7 @@
"02-18",
"02-20",
"03-title",
"03-01",
"03-05",
"03-09",
"03-12",