Mon Jun 14 2021 19:13:48 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-06-14 19:13:51 +01:00
parent d83d047172
commit 2b7a389e10
3 changed files with 2 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 6 Gẹ́gẹ́bí ẹ ti gba Krístì ní Olúwa, ẹ rìn nínú Rẹ̀. \v 7 Ẹ fi gbòngbo múlẹ̀ nínú Rẹ̀, kí á gbé yín ró lóríí Rẹ̀, kí ẹ fi ẹsẹ̀ múlẹ̀ nínú ìgbàgbọ́ gẹ́gẹ́ bí a ti kọ́ yín, ki ẹ sì pọ̀ si nínú ìdúpẹ́.
\v 6 Gẹ́gẹ́ bí ẹ ti gba Krístì ní Olúwa, ẹ rìn nínú Rẹ̀. \v 7 Ẹ fi gbòngbo múlẹ̀ nínú Rẹ̀, kí á gbé yín ró lóríí Rẹ̀, kí ẹ fi ẹsẹ̀ múlẹ̀ nínú ìgbàgbọ́ gẹ́gẹ́ bí a ti kọ́ yín, ki ẹ sì pọ̀ si nínú ìdúpẹ́.

View File

@ -1 +1 @@
\v 8 Ẹ f'iyèsi kí ẹnikẹ́ni má fi ọ̀rọ̀ àròsọ àti ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn tó dá lórí àṣà ènìyàn mú yín ní ìgbèkùn, eléyìí tí ó ní ìdàpọ̀ àwọn ẹ̀mí ayé yii sugbọ́n tí kó bá ìlàna Kristi mú. \v 9 Nitori ni inú Rẹ̀ ni ẹ̀kùnrẹrẹ Ọlọrun ngbé ninú ara.
\v 8 Ẹ f'iyèsi kí ẹnikẹ́ni má fi ọ̀rọ̀ àròsọ àti ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn tó dá lórí àṣà ènìyàn mú yín ní ìgbèkùn, eléyìí tí ó ní ìdàpọ̀ àwọn ẹ̀mí ayé yìí ṣùgbọ́n tí kò bá ìlàna Krístì mu. \v 9 Nitori ni inú Rẹ̀ ni ẹ̀kùnrẹrẹ Ọlọrun ngbé ninú ara.

View File

@ -53,7 +53,6 @@
"02-01",
"02-04",
"02-06",
"02-08",
"02-10",
"02-13",
"02-16",