adesinaabegunde_yo_2th_text.../03/01.txt

1 line
502 B
Plaintext

\c 3 \v 1 Nísinsìnyí ará, ẹ máa gbàdúrà fún wa pé kí ọ̀rọ̀ Ọlórun tàn jáde ní kánkán kí ó si di ṣíse lògo, gẹ́gẹ́ bí ó tise wà láàrin yín. \v 2 Ẹ máa gbàdúrà pé kí Ọlọ́run gbàwá lọ́wọ̀ àwọn ìkà àti àwọn ènìyàn búburú, nítorí kìí ṣe gbogbo àwọn ènìyàn ni ó gbàgbọ́. \v 3 Ṣùgbọ́n olódodo ni Olúwa, Òhun yóò fi ẹsẹ̀ rẹ múlẹ̀, yóò sì gbà ọ́ lọ́wọ́ àwọn ẹni búburú.