adesinaabegunde_yo_2th_text.../02/13.txt

1 line
546 B
Plaintext

\v 13 Ṣùgbọ́n ó yẹ kí á sábà máa fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run nítorí, ẹ̀yin arákùnrin tí olúwa fẹ́. Nítorí Ọlọ́run yànyín sí èso àkọ́soní ìsọdimímọ́ àti ìgbàlà nínú Ẹ̀mí àti ìgbàgbọ́ nínú òtítọ́. \v 14 Èyí ni ohun tí ò pè yín fún pé nípa ìhìnrere wa láti le gba ògo ti Jésù kristì Olúwa wa. \v 15 Nítorínáà, ará, ẹ dúró sinsin. Kí ẹ sì dì ẹ̀kọ́ tí a ti kọ yín mú sinsin, bóyá nípa ọ̀rọ̀ tàbí ìwe wa tí a kọ si yín.