adesinaabegunde_yo_2th_text.../02/08.txt

1 line
527 B
Plaintext

\v 8 Nígbànáà ni a ó fi ẹni ẹ̀ṣẹ̀ náà hàn, ẹnití Jésù Olúwa yóò fi èémí ẹnu rẹ̀ pá. Olúwa yóò mu wá sí asán nípa ìfihàn bíbọ̀ ọ rẹ̀. \v 9 Ọkùnrin ẹni ẹ̀ṣẹ ẹ̀ nì tí yóò wá nítorí iṣẹ́ sátánì pẹ̀lú gbogbo agbára, àmìn, àti èké iṣẹ́ gbogbo, \v 10 àti pẹ̀lú gbogbo ìtànjẹ àìsòdodo. Nǹkan wọ̀nyí yóò wà fún àwọn tí ń sègbé, nítorí tí wọn kò gba ìfẹ́ òtítọ́ tí ó wà fún ìgbàlà wọn.