adesinaabegunde_yo_2th_text.../02/03.txt

1 line
462 B
Plaintext

\v 3 Ẹ máse jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tàn yín jẹ lọ́nàkọnà. Nítorípé kí yóò wá bíkòsepé ọjọ́ ìyapa bá dé, tí a ó sì fi ẹlẹ́ṣẹ̀ náà hàn, ọmọ ìparun. \v 4 Òun ni ẹni tí ń lòdì tí ó sì ń gbé ara rẹ̀ ga sí ohungbogbo tí à ń pè ní Ọlọ́run tàbí tí à ń sìn. Ní àbáyọrí pé, ó jòkó nínú tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run ó sì tún fi ara rẹ̀ han pé Ọlọ́run ni Òun.