adesinaabegunde_yo_2pe_text.../03/14.txt

1 line
680 B
Plaintext

\v 14 Nítorínà, olùfẹ́, nígbàtí ẹ sì ń retí nkán wọ̀nyí, ẹ sa ipá yín láti wà nì aláìlábàwọ́n àti aláìlábùkù ní iwájú Rẹ̀, ní àláfíà. \v 15 Bẹ́ẹ̀ni kí ẹ rí sùúrù Olúwa wa sí ìgbàlà, bí olùfẹ́ arákùnrin Pọ́ọ̀lù ti kọ̀wé síi yín, bíi ọgbọ́n tí a fi fún-un. \v 16 Pọ́ọ̀lù sọ gbogbo ǹkan wọ̀nyí nínú àwọn lẹ́ẹ̀ta rẹ̀, nínú èyí tí àwọn ohun kọ̀kan ṣòro láti nì òye rẹ̀. Ọkùnrin aláímọ̀kan àti oníṣégeṣège túmọ̀ àwọn ǹkan wọ̀nyí, bí wọ́n ṣeṣe àwọn ìwé mímọ́ míràn, sí ìparun ti wọn.