adesinaabegunde_yo_2pe_text.../03/05.txt

1 line
469 B
Plaintext

\v 5 Tìfẹ́tìfẹ́ wọ́n gbàgbé wípé ọ̀run àti ayé tẹ̀lẹ̀ láti inú omi àti nípa omi tipẹ́tipẹ́ nípa àsẹ Ọlọ́run , \v 6 àti nípa àwọn wọ̀nyí, ayé ìgbànáà dí ìparun, pẹ̀lú ìkún omi. \v 7 Ṣùgbọ́n nísinsìnyí àwọn ọ̀run àti ayé wà ní ìpamọ́ fún iná nípa òfin kanáà. Wọ́n wà ni ìpamọ́ fún ọjọ́ ìdájọ́ àti ìparun tì àwọn ènìyàn aláíwà bi Ọlórun.