adesinaabegunde_yo_2pe_text.../02/07.txt

1 line
521 B
Plaintext

\v 7 Ṣùgbọ́n fun Lóòtì olódodo, tí wọ́n nilára pẹ̀lu ìwà àwọn ènìyàn arufin nínu ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́, Ọlọ́run kóoyọ. \v 8 Fún ọkùnrin olódodo náà, tí ńgbé ní àrin wọn ní ọjọ́ dé ọjọ́, la pọ́n lójú ní ọkàn òdodo rẹ̀ nítorí ǹkan tí ó rí àti tí ó gbọ́. \v 9 Olúwa mọ bí ó tín yọ àwon ènìyàn bí Ọlọ́run kúrò nínu ìdánwò, àti láti mú àwọn ènìyàn aláìsòdodo fún ìjìyà ní ọjọ́ ìdájọ́.