adesinaabegunde_yo_2pe_text.../02/01.txt

1 line
572 B
Plaintext

\v 1 Àwọn wòlíì èké tọ àwọn ènìyàn wá, àti àwon olùkọ́ èké yóò sì tọ̀ yín wá.Wọn ó fi ìkọ̀kọ̀ mú ìparun èké pẹ̀lú wọn wá, wọn yó sì sẹ́ olúwa wọn eni tí ó ràn wọ́n. Wọ́n sì mú ìparun wá sórí ara wọn. \v 2 Púpọ̀ ni yóó tẹ̀lé ìfẹ́kùfẹ́ wọn, àti nípa wọn ọ̀nà òtítọ́ yóò sì di búburú. \v 3 Pẹ̀lú wòbìà wọ́n yò jẹ èrè lára yín pẹ̀lú ọ̀rọ́ ẹ̀tàn. Ìdálẹ́bi wọn kò kín pẹ́ títí; ìparun wọn kò kín-ń sùn.