adesinaabegunde_yo_2pe_text.../01/19.txt

1 line
894 B
Plaintext
Raw Permalink Blame History

This file contains invisible Unicode characters

This file contains invisible Unicode characters that are indistinguishable to humans but may be processed differently by a computer. If you think that this is intentional, you can safely ignore this warning. Use the Escape button to reveal them.

\v 19 A ní ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tí ó dájú. Ẹ ṣe dárádára láti ṣe àkíyèsí rẹ̀. Ó dàbí àtùpà tín taná nínú òkùnkùn títí di òwúrọ̀ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ gbésékè nínu ọkàn rẹ \v 20 Ẹ kọ́kọ́ mọ èyí, wípé kòsí ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tó jẹ́ tí ìtumọ̀ ènìyàn kan. \v 21 Nítorí kòsí àsọtẹ́lẹ̀ tó wá nípa ìfẹ́ ènìyàn. Dípò, àwọn ènìyàn tí Ẹ̀mí Mímọ́ tó sọ jáde látọ̀dọ Ọlọ́run.