adesinaabegunde_yo_2pe_text.../01/12.txt

1 line
629 B
Plaintext

\v 12 Nítorínà èmi yóò ṣetán nígbàgbogbo láti máarán-yín létí àwọn ǹkan wọ̀nyí, bótilẹ̀jẹ́pé ẹ mọ̀ wọ́n, àti bótilẹ̀jẹ́pé ẹ ti dàgbà nínú òtítọ́ nísisìnyí. \v 13 Mo lé rò pé ó tọ́ fún mi láti ru yín sókè pẹ̀lú ìrántí nípa àwọn ǹkan wọ̀nyí, ní ìwọ̀n ìgbà tí mo wà nínu àgọ́ yìí. \v 14 Nítorí mo mọ̀ pé láìpẹ́, èmi yóò yọ àgọ́ mí, bí Olúwa wa Jésù Krístì tí fí hàn mí. \v 15 Èmi yóò sa ipá mi fún-un yín láti lè ma rántí àwọn ǹkan wọ̀nyí lẹ́yìn tí mo bá lọ tán.