adesinaabegunde_yo_2pe_text.../01/03.txt

1 line
463 B
Plaintext

\v 3 Gbogbo ohun tí óníṣe pẹ̀lú agbára àtòkèwá fún ìyè àti ìwàbíi-Ọlórun lati fi fún wa nípa ọgbọn Ọlórun, Ẹni tí óti pèwá nípa ògo àti ìwà rerẹ̀ Rẹ̀. \v 4 Nípa ìwọ̀nyí, Óti fún wa ní ìlérí ńlá àti èyítí óse iyebíye, kí ìwọ leè jẹ́ alábàápín nínú-un ara àtòkèwá, bí ó ṣe ń yọ kúrò nínu ìbàjẹ́ tí ó wà nínu ayé nítorí àwọn ìfẹ́-ọkàn búburú.