adesinaabegunde_yo_1ti_text.../01/15.txt

1 line
565 B
Plaintext

\v 15 Ìhìnrere yìí seé gbáralé, ósì ye fún gbígbà, pé Jésù Krístì wá sáyé láti wa gba ẹlẹ́sẹ̀ là, mo sì jé ẹlẹ́sẹ̀ jùlo. \v 16 Ṣùgbọ́n fún ìdí èyí morí àánú gbà, pé nínú mi, ọ́pòlopò, Krístì Jésù le ṣàfihàn gbogbo ìrẹ̀lẹ̀. Ósì se èyí gẹ́gẹ́ bíi àpẹrẹ fún àwon ti yìó gbẹ́kẹ̀ wọn lée fún ìyè ayérayé. \v 17 Nísinsìnyí sí ọba ayérayé, Ẹni àìdibàmí, Eni àìrì, Olórun kan ṣoṣo, nikí olá àti ògo ye títí láí àti láí. Àmín