adesinaabegunde_yo_1ti_text.../04/09.txt

1 line
306 B
Plaintext

\v 9 Òdodo ni ọ̀rọ̀ yí, ó sì yẹ fùn ìtẹ́wọ́gbà tokàntokàn. \v 10 Nítorí fún èyí ni àwa sì ń ṣiṣẹ́ kárakára. Nítorí àwa ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Ọlọ́run alààyè, eni tí ń ṣe Olùgbàlà gbogbo ènìyan, pàápáà jùlọ àwọn onígbàgbọ́.