\v 16 Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó le jiyàn wípé ìjìnlẹ̀ ńlá ni òtítọ́ ti Ọlọ́run ii hàn. " Ó fara hàn nínú ẹran ara, ó gba ìdáláre nípa Ẹ̀mí, àwọn ángẹ́lì rí i, wọ́n kéde Rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀ èdè, asì gbà á sókè nínú ògo.