adesinaabegunde_yo_1ti_text.../03/11.txt

1 line
512 B
Plaintext

\v 11 Àwọn obìnrin lọ́nà kan náà gbọdọ̀ lọ́lá. Wọn kò gbọdọ̀ jẹ́ asọ̀rọ̀ òdì. Wọ́n gbọdọ̀ jẹ̀ oníwọ̀ntunwọ̀nsì àti olóòtọ́ ní gbogbo ọ̀nà. \v 12 Àwọn díákónì gbọdọ̀ jẹ́ ọkọ oní ìyàwó kan. Wọ́n gbọdọ̀ le ṣe àmójútó àwọn ọmọ wọn àti ilé wọn dáradára. \v 13 Nítorí àwọn tì ó ti sìn dáradára gba orúkọ rere àti ìgboyà ńlá nínú ìgbàgbọ́ tí ó wà nínú Krístì Jésù.