adesinaabegunde_yo_1ti_text.../03/08.txt

2 lines
432 B
Plaintext

\v 8 Àwọn díákónì, pẹ̀lú gbọdọ̀ lọ́lá, kìí se ẹlẹ́nu méjì. Wọn kò gbọdọ̀ jẹ́ ọ̀mùtí para tàbí olójú kòkòrò.
\v 9 Wọ́n gbọdọ̀ pa òtítọ́ ìgbàgbọ́ tí a fi hàn mọ́ pẹ̀lú ẹ̀rí ọkàn tó mọ́. \v 10 Wọ́n gbọdọ̀ kọ́kọ́ di ẹni ìtẹ́wọ́gbà, nígbànáà wọ́n gbọdọ́ ṣe isẹ́ ìránṣẹ́ nítorí wọn kò lẹ́bi.