adesinaabegunde_yo_1ti_text.../03/01.txt

3 lines
555 B
Plaintext

\c 3 \v 1 Ọ̀rọ̀ yí gbọdọ̀ jẹ̀ òtítọ́: Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ láti jẹ́ alámòjútó, oun fẹ́ isẹ́ rere.
\v 2 Nítorínà alámòjútó gbọdọ̀ wà láì lẹ́bi. Ó gbọdọ̀ jẹ̀ ọkọ aláya kan. Ó gbọdọ̀ jẹ̀ oníwọ̀ntunwọ̀nsì, olórí pípé, omolúàbí, ẹni tí ń se àlejò. Ó gbọdọ̀ leè kọ́ ni.
\v 3 Kò gbọdọ̀ jẹ̀ ọ̀mùtí para, oníjà, ṣùgbọ́n kí ó jẹ́ oníwà pẹ̀lẹ́ àti alálàáfíà. Kò gbọdọ̀ jẹ́ ẹni tó fẹ́ràn owó.