adesinaabegunde_yo_1ti_text.../02/13.txt

1 line
360 B
Plaintext

\v 13 Nítorí Ádámù ni akọ́kọ́ dá kí, á tó dá Éfà. \v 14 A kò tan Ádámù jẹ ṣùgbọ́n obìnrin náà ni a tàn jẹ pátápátá sínú àìsedédé. \v 15 Síbẹ̀síbẹ̀, a ó gbàálà nípa ọmọ bíbí, bí wọ́n bá tẹ̀sìwájú nínú ìgbàgbọ́, àti ìfẹ́ ati ìwẹ̀nùmọ́ pẹ̀lú ọkàn tí ó péye.