adesinaabegunde_yo_1ti_text.../02/05.txt

1 line
474 B
Plaintext

\v 5 Nítorí Ọlọ́run kan ni ó wà, alárinnà kan ni ó sì wà làárín Ọlọ́run àti ènìyàn, ọkùnrin náà Krístì Jésù. \v 6 Ó fi ara rẹ̀ sílẹ̀ ní ìràpadà fún gbogbo ènìyàn gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí ní àkókò tí ó tọ́. \v 7 Fún ìdí èyí, a sọ èmi tìkaraàmi di ìránsẹ́ ati àposítélì. Èmí ń sọ òtítọ́. Èmi kò parọ́. Èmi jẹ́ olùkọ́ àwọn Hélénì ni ìgbàgbọ́ àti ní òtítọ́.