adesinaabegunde_yo_1ti_text.../01/18.txt

1 line
470 B
Plaintext

\v 18 Òfin yìí ni mofi fún ọ, Tímótíù ọmọ mi, ní ìbamu pẹ̀lú ìsotẹ́lẹ̀ èyí tí ati sọ nípa rẹ tẹ́lè, pé, kí ìwọ leja ìjà rere náà, \v 19 di ìgbàgbọ́ ati ẹ̀rí ọkàn tòótọ́ mú. Ní kíkọ èyí, àwọn kán ti pàdánù ìgbàgbọ́ wọn. \v 20 Àwọn ènìyàn bi Hímánéusì àti Alẹsándérù, tí mo fàlé Sàtánì lọ́wọ́ kí wọ́n leè kẹ́ẹ̀kọ́ láti máa sọ̀rọ̀ òdì.