adesinaabegunde_yo_1ti_text.../01/15.txt

1 line
603 B
Plaintext

\v 15 Ìyìnrere yìí seé gbáralé, ósì yẹ fún gbígbà, pé, Jésù Krístì wá sáyé láti wá gba ẹlẹ́sẹ̀ là, mo sì jẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ jùlọ. \v 16 Ṣùgbọ́n fún ìdí èyí morí àánú gbà, pé nínú mi, ọ̀pọ̀lọpọ̀, Krístì Jésù leè ṣàfihàn gbogbo ìrẹ̀lẹ̀. Ósì ṣe èyí gẹ́gẹ́ bíi àpẹrẹ fún àwon ti yóò gbẹ́kẹ̀ wọn lée fún ìyè ayérayé. \v 17 Nísinsìnyí sí ọba ayérayé, Ẹni àìdibàjẹ́, Ẹni àìrì, Ọlọ́run kanṣoṣo, nikí ọlá àti ògo ye títí láí àti láíláí. Àmín.