adesinaabegunde_yo_1ti_text.../01/03.txt

1 line
444 B
Plaintext

\v 3 Dúró sí Éfésù kí o lè máa pàṣẹ fún àwọn ènìyàn kan, kìí wón máṣe kọ́ ìlànà tí ó yàtọ̀ sí bí moti kọ́ ọ nígbàtí mò ń tẹ̀síwájú lo sí Masidóníà. \v 4 Bákanáà kí wọn máse fiyèsí àwọn ìtàn àti àwọn ìtàn ìrandíran tí kò lópin. Àríyànjiyàn asán ni eléyìí má ńfà dípo kí ó ran ètò Ọlọ́run lọ́wọ́, tíí ṣe nípa ìgbàgbọ́.