Thu Jun 27 2019 12:18:38 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
6ba29d31fe
commit
d592850187
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 5 Nísinsìyí, ìfojúsùn ti òfin yìí ni ìfẹ́ láti inú ọkàn tòótọ́, láti inú ẹ̀rí-ọkàn tó péye àti láti inú ìgbàgbọ́ àìṣẹ̀tàn. \v 6 Àwọn ẹlòmíràn ṣìnà, wọ́n sì ti yà kúrò nínú nǹkan wọ̀nyí sínú sísọ ọ̀rò òmùgọ̀. \v 7 Wọ́n fẹ́ jẹ́ Olùkọ́ òfin náà ṣùgbọ́n wọn kò ní òye ohun tí àwọn tìkarawon ńwí tàbí ohun ti wọ́n gbàgbó. \v 8 Ṣùgbọ́n àwá mọ̀ pé òfin dára bí abá sẹ àmúlò rè ní ọ̀nà tí ó bá òfin mu.
|
||||
\v 5 Nísinsìyí, ìfojúsùn ti òfin yìí ni ìfẹ́ láti inú ọkàn tòótọ́, láti inú ẹ̀rí-ọkàn tó péye àti láti inú ìgbàgbọ́ àìṣẹ̀tàn. \v 6 Àwọn ẹlòmíràn ṣìnà, wọ́n sì ti yà kúrò nínú nǹkan wọ̀nyí sínú sísọ ọ̀rò òmùgọ̀. \v 7 Wọ́n fẹ́ jẹ́ Olùkọ́ òfin náà ṣùgbọ́n wọn kò ní òye ohun tí àwọn tìkarawon ńwí tàbí ohun ti wọ́n gbàgbó. \v 8 Ṣùgbọ́n àwá mọ̀ pé òfin dára bí abá ṣe àmúlò rẹ̀ ní ọ̀nà tí ó bá òfin mu.
|
Loading…
Reference in New Issue