Mon Jul 08 2019 00:00:59 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
450643307d
commit
af13443ec2
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 6 Ìwọ yóó jẹ́ ìránṣẹ́ Jésù Kristì tí ó dára tí ìwọ bá gbé gbogbo àwọn ǹkan wọ̀nyí síwaju àwọn ará. Nítorí à ńbọ́ ọ pẹ̀lú àwọn òrò ìgbàgbọ́ àti pẹ̀lú ìkọ́ni tí ó yè koro tí ó ti tẹ̀lé. \v 7 Ṣùgbọ́n kọ gbògbo àwọn àlọ́ àti ìtàn tí kò wúlò. Nípò rẹ̀, kọ́ arà rẹ ní ìwà bí Ọlọ́run. \v 8 Ìwúlò eré ìdárayá díè ni, ṣùgbọ́n ìwà bíi Ọlọ́run wúlò fún ohun gbogbo. Óní èrè fún aye yii nisinsinyi ati fun aye eyi too n bo.
|
||||
\v 6 Ìwọ yóó jẹ́ ìránṣẹ́ Jésù Kristì tí ó dára tí ìwọ bá gbé gbogbo àwọn ǹkan wọ̀nyí síwaju àwọn ará. Nítorí à ńbọ́ ọ pẹ̀lú àwọn òrò ìgbàgbọ́ àti pẹ̀lú ìkọ́ni tí ó yè koro tí ó ti tẹ̀lé. \v 7 Ṣùgbọ́n kọ gbògbo àwọn àlọ́ àti ìtàn tí kò wúlò. Nípò rẹ̀, kọ́ arà rẹ ní ìwà bí Ọlọ́run. \v 8 Ìwúlò eré ìdárayá díè ni, ṣùgbọ́n ìwà bíi Ọlọ́run wúlò fún ohun gbogbo. Óní èrè fún ayé yìí nísinsìnyí àti fún ayé èyí tó ńbọ̀.
|
Loading…
Reference in New Issue