Thu Jun 27 2019 12:32:38 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 12:32:40 +01:00
parent a1e2466f31
commit 94351ec220
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 15 Ìyìnrere yìí seé gbáralé, ósì yẹ fún gbígbà, pé, Jésù Krístì wá sáyé láti wá gba ẹlẹ́sẹ̀ là, mo sì jẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ jùlọ. \v 16 Ṣùgbọ́n fún ìdí èyí morí àánú gbà, pé nínú mi, ọ̀pọ̀lọpọ̀, Krístì Jésù leè ṣàfihàn gbogbo ìrẹ̀lẹ̀. Óṣì se èyí gẹ́gẹ́ bíi àpẹrẹ fún àwon ti yóò gbẹ́kẹ̀ wọn lée fún ìyè ayérayé. \v 17 Nísinsìnyí sí ọba ayérayé, Ẹni àìdibàjẹ́, Ẹni àìrì, Ọlóọ́run kan ṣoṣo, nikí ọlá àti ògo ye títí láí àti láí. Àmín.
\v 15 Ìyìnrere yìí seé gbáralé, ósì yẹ fún gbígbà, pé, Jésù Krístì wá sáyé láti wá gba ẹlẹ́sẹ̀ là, mo sì jẹ́ ẹlẹ́sẹ̀ jùlọ. \v 16 Ṣùgbọ́n fún ìdí èyí morí àánú gbà, pé nínú mi, ọ̀pọ̀lọpọ̀, Krístì Jésù leè ṣàfihàn gbogbo ìrẹ̀lẹ̀. Ósì ṣe èyí gẹ́gẹ́ bíi àpẹrẹ fún àwon ti yóò gbẹ́kẹ̀ wọn lée fún ìyè ayérayé. \v 17 Nísinsìnyí sí ọba ayérayé, Ẹni àìdibàjẹ́, Ẹni àìrì, Ọlọ́run kanṣoṣo, nikí ọlá àti ògo ye títí láí àti láíláí. Àmín.

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Òfin yìí ni mofi fún ọ, Tímótíù ọmọọ̀mi, ní ìbamu pẹ̀lú ìsotẹ́lẹ̀ èyí tí ati sọ nípa rẹ tẹ́lè, pé kí ìwọ leja ìjà rere náà, \v 19 di ìgbàgbọ́ ati èrí ọkàn tòótó mu. Ní kíkọ èyí, àwọn kán ti pàdánù ìgbàgbọ́ wọn. \v 20 Àwọn ènìyàn bi Hímánéusì àti Alesándérù, tí mo fàlé sàtánì lọ́wọ́ kí wón leè kẹ́ẹ̀kọ́ láti máa sọ̀rọ̀ òdì.
\v 18 Òfin yìí ni mofi fún ọ, Tímótíù ọmọ mi, ní ìbamu pẹ̀lú ìsotẹ́lẹ̀ èyí tí ati sọ nípa rẹ tẹ́lè, pé kí ìwọ leja ìjà rere náà, \v 19 di ìgbàgbọ́ ati èrí ọkàn tòótó mu. Ní kíkọ èyí, àwọn kán ti pàdánù ìgbàgbọ́ wọn. \v 20 Àwọn ènìyàn bi Hímánéusì àti Alesándérù, tí mo fàlé sàtánì lọ́wọ́ kí wón leè kẹ́ẹ̀kọ́ láti máa sọ̀rọ̀ òdì.