Mon Oct 14 2019 09:35:46 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-14 09:35:47 +01:00
parent 3365ab356e
commit 824e78d7d3
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Nísisìyí àwọn tó fẹ́ di ọlọ́rọ̀ ṣubú sínú ìdánwò, sínu pàkúté. Wọ́n ṣubú sínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òmùgò àti ìfẹ́kúfẹ̌ tí ó ń panilára, àti ohunkóhun tó má ń mu àwọn èyàn ri sínu ìparun. \v 10 Nítorí ìfẹ́ owó jé gbongbo gbogbo ibi.Âwọn ǹkan tí wọ́n ti nífe rẹ̀ ti ṣìnà kúrò nínu ìgbàgbọ́ wọ́n ti gún ra wọn pèlú ìbìnújé tó pọ̀.
\v 9 Nísisìyí àwọn tó fẹ́ di ọlọ́rọ̀ ṣubú sínú ìdánwò, sínu pàkúté. Wọ́n ṣubú sínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òmùgò àti ìfẹ́kúfẹ̌ tí ó ń panilára, àti ohunkóhun tó má ń mú àwọn ènìyàn rì sínú ìparun àti ègbé. \v 10 Nítorí ìfẹ́ owó jé gbòǹgbò ohun bu gbogbo ibi.Âwọn ǹkan tí wọ́n ti nífe rẹ̀ ti ṣìnà kúrò nínu ìgbàgbọ́ wọ́n ti gún ra wọn pèlú ìbìnújé tó pọ̀.