Thu Jun 27 2019 12:26:38 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 12:26:40 +01:00
parent 40150c6f26
commit 73ef1b2f57
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Àwa mọ èyí pé, a kòṣe òfin fún àwọn olótǐtọ́ ènìyàn, bíkòse fún àwọn aláìlófin àti àwọn aláìgbọràn, fún àwọn aláìwàbí Ọlọ́run àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, àti fun àwọn aláìlọ́lọ́run, àti gàbàgebè. Asé é fún àwọn tí ó pa bàbá àti ìyá won, àwọn apànìyàn, \v 10 Fún àwọn aláìlemáradúró, onísekúse, àwọn agínigbé ṣẹrú, fún òpùrọ́, fún àwọn ajẹ́rìí-èké àti ohunkóhun tí ó lòdì sí ìlànà tí ó tọ́. \v 11 Àwọn ìlànà yìí ń tèlé ìhìnrere ti Ọlọ́run olùbùkún nínú èyí tí a gbélé mi lọ́wọ́.
\v 9 Àwa mọ èyí pé, a kòṣe òfin fún àwọn olótǐtọ́ ènìyàn, bíkòse fún àwọn aláìlófin àti àwọn aláìgbọràn, fún àwọn aláìwàbí Ọlọ́run àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, àti fun àwọn aláìlọ́lọ́run, àti alágàbàgebè. Asé é fún àwọn tí ó pa bàbá àti ìyá won, àwọn apànìyàn, \v 10 Fún àwọn aláìlemáradúró, onísekúse, àwọn ajínigbé ṣẹrú, fún òpùrọ́, fún àwọn ajẹ́rìí-èké àti ohunkóhun tí ó lòdì sí ìlànà tí ó tọ́. \v 11 Àwọn ìlànà yìí ń tẹ̀lé ìyìnrere ti Ọlọ́run olùbùkún nínú èyí tí a gbélé mi lọ́wọ́.