diff --git a/02/13.txt b/02/13.txt index 1cb8b21..e2d3167 100644 --- a/02/13.txt +++ b/02/13.txt @@ -1 +1 @@ -\v 13 Nítorí Ádámù ni akọ́kọ́ dá kí, á tó dá Éfà. \v 14 A kò tan Ádámù jẹ ṣùgbọ́n obìnrin náà ni a tàn jẹ pátápátá sínú àìsedédé. \v 15 Síbẹ̀síbẹ̀, a ó gbàálà nípa omo bíbí, bíwọ́n bá tẹ̀sìwájú nínú ìgbàgbọ́, àti ìfé ati ìwènùmó pèlú ọkàn tí ó péye. \ No newline at end of file +\v 13 Nítorí Ádámù ni akọ́kọ́ dá kí, á tó dá Éfà. \v 14 A kò tan Ádámù jẹ ṣùgbọ́n obìnrin náà ni a tàn jẹ pátápátá sínú àìsedédé. \v 15 Síbẹ̀síbẹ̀, a ó gbàálà nípa ọmọ bíbí, bíwọ́n bá tẹ̀sìwájú nínú ìgbàgbọ́, àti ìfẹ́ ati ìwènùmọ́ pèlú ọkàn tí ó péye. \ No newline at end of file