Mon Oct 14 2019 09:49:43 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-14 09:49:43 +01:00
parent 0b9bad10eb
commit 14fc550709
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 15 Ọlórun yó fi ara Rẹ̀ hàn ni àsìkò tó tọ́--- Ọlórun, Olùbùkún nì, Agbára kan soso, Ọba tó wà, Olúwa tó joba. \v 16 Òun nìkan ló jẹ́ àìkú tó sin jọba nínú ìmólẹ̀ àdììtú. Èyàn kankan kò ri tàbí wòó. Fún òun ni ìyìn àti agbára ayérayé. Àmín
\v 15 Ọlórun yó fi ara Rẹ̀ hàn ni àsìkò tó tọ́--- Ọlórun, Olùbùkún nì, Agbára kan soso, Ọba tó wà, Olúwa tó joba. \v 16 Òun nìkan ló jẹ́ àìkú tó sin gbé nínú ìmólẹ̀ tí a kò le è sún mọ́. Ènìyàn kankan kò ri tàbí le wòó. Fún òun ni ìyìn àti agbára ayérayé. Àmín