Biblica_yoOBYO17/A0FRTyoOBYO17.SFM

68 lines
5.9 KiB
Plaintext
Raw Permalink Blame History

This file contains invisible Unicode characters

This file contains invisible Unicode characters that are indistinguishable to humans but may be processed differently by a computer. If you think that this is intentional, you can safely ignore this warning. Use the Escape button to reveal them.

\id FRT - Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible (Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
\rem Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.
\periph Half Title Page
\mt1 BÍBÉLÌ MÍMỌ́
\mt2 Ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
\pc Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
\pc Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
\periph Title Page NT
\mt1 BÍBÉLÌ MÍMỌ́
\mt2 Ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
\b
\mt2 Májẹ̀mú Tuntun
\b
\pc Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible
\pc Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
\b
\periph Publication Page
\pc Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™
\pc Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 Biblica, Inc.
\b
\pc Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™
\pc Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.
\b
\pc “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission.
\b
\b ――――――
\b
\m This work is made available under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 4.0 International License (CC BY-SA). To view a copy of this license, visit http://creativecommons.org/licenses/by-sa/4.0 or send a letter to Creative Commons, PO Box 1866, Mountain View, CA 94042, USA.
\b
\mi Biblica® is a trademark registered by Biblica, Inc., and use of the Biblica® trademark requires the written permission of Biblica, Inc. Under the terms of the CC BY-SA license, you may copy and redistribute this unmodified work as long as you keep the Biblica® trademark intact. If you modify a copy or translate this work, thereby creating a derivative work, you must remove the Biblica® trademark. On the derivative work, you must indicate what changes you have made and attribute the work as follows: “The original work by Biblica, Inc. is available for free at www.biblica.com and open.bible.”
\b
\mi Notice of copyright must appear on the title or copyright page of the work as follows:
\b
\pc Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™
\pc Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 Biblica, Inc.
\b
\pc Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™
\pc Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.
\b
\pc “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission.
\b
\mi You must also make your derivative work available under the same license (CC BY-SA).
\b
\m If you would like to notify Biblica, Inc. regarding your translation of this work, please contact us at https://open.bible/contact-us.
\b
\b ――――――
\b
\periph Preface
\mt1 Ọ̀rọ̀ Àkọ́sọ
\p Èròǹgbà atúmọ̀ tuntun Bíbélì Yorùbá yìí ni láti mú àwọn òtítọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run dé àrọ́wọ́tó àwa ènìyàn tí ń kà á ní èdè Yorùbá tí ó rọrùn, tí yóò sì mú kí ohun tí a ń kà yé ni yékéyéké láìlo ògbifọ̀. Èdè Yorùbá ti kúrò ní ti ẹ̀yà Yorùbá nìkan, ó ti di èyí tí a ń kà láàrín gbogbo ẹ̀yà àgbáyé. Ìdí èyí ni a fi fi èdè Yorùbá ti ẹni dúdú àti funfun le kà kọ ọ́, fún ìtẹ̀síwájú àti ìgbòòrò ìyìnrere Jesu Kristi Olúwa wa.
\p Bíbélì àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ ìpìlẹ̀ iṣẹ́ atúmọ̀ Bíbélì ní èdè mìíràn sí èdè Yorùbá ni èyí tí Bíṣọ́ọ̀bù Samuẹli Àjàyí Crowther ṣe ní ọdún 1884. Yorùbá igba ọdún kì í ṣe èyí tí àwọn olùkà èdè Yorùbá òde-òní lè kà ní àkàyé. Èdè Yorùbá jẹ́ èdè tí wọn ń kọ́, tí wọ́n ń kà láàrín àwọn ẹ̀yà mìíràn káàkiri gbogbo àgbáyé, èyí sì jẹ́ ọ̀kan lára èrò tó ti inú gbígbèrú àti ìdàgbàsókè èdè Yorùbá wá fún àtúntúmọ̀ yìí. Lóòrèkóòrè ni àwọn onímọ̀ ń ṣe àtúnṣe tí ó yẹ lórí ìlànà àkọtọ́ èdè Yorùbá kí ó bá lè sọ kíkà àti yíyéni rẹ̀ di ìrọ̀rùn fún ẹ̀yà Yorùbá àti fún àwọn ẹ̀yà gbogbo tó ń ka èdè Yorùbá, èyí kò yẹ kí ó yọ Ìwé Mímọ́ sílẹ̀ ni èrò mìíràn fún àtúntúmọ̀ tuntun yìí.
\p Nínú àtúntúmọ̀ Bíbélì Yorùbá tuntun yìí, ẹ ó ṣe alábòápàdé àwọn àtúnṣe sí orúkọ àwọn ìwé kan, àwọn ènìyàn kan àti àwọn ibi kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú ìtumọ̀ wọn nínú èdè tí a ti kọ́ bá wọn pàdé. A túnṣe àfikún àwọn àfihàn ẹsẹ àti àkọlé olóríjorí nínú àtúntúmọ̀ Bíbélì Yorùbá tuntun yìí láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ìtètèyéni ọ̀rọ̀ Ọlọ́run náà. A fi ábídí tọ́ka sí àwọn ẹsẹ Bíbélì tí ó lè fún wa ní òye kíkún lórí kókó tí a bá ń kà nínú Bíbélì. A ṣe èyí láti mú kí àwọn tó ń kà á lè fún ohun tí wọn ń kà ní ìtumọ̀ tí ó yẹ láìwá ìwé atúmọ̀ Bíbélì kiri.
\p Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run jẹ́ mímọ́, ó ṣe iyebíye, ó sì ní ìyè lórí, ó ní agbára, òtítọ́ rẹ̀ tí kì í kú, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣá, ó sì ń mú ìrètí àti ìdánilójú ìyè àìnípẹ̀kun wá. Bí a ṣe ń gbé àtúntúmọ̀ tuntun yìí jáde, àdúrà wa ni pé kí Ẹ̀mí Mímọ́ fún ẹnìkọ̀ọ̀kan tí ó ń wá òtítọ́ yìí ní ìsọdọ̀tun, kí ó sì mú wa yẹ fún ayérayé ìjọba rẹ̀ tí kò ní ìpẹ̀kun, bí a ti ń mu nínú kànga omi ìyè yìí. Àmín.
\periph Table of Contents
\mt1 ÌTỌ́KA ÀKÓÓNÚ ÀWỌN ÌWÉ
\ms1 Májẹ̀mú Láéláé
\li1 Gẹnẹsisi ~~ #
\li1 …
\li1 Malaki ~~ #
\ms1 Májẹ̀mú Tuntun
\li1 Matiu ~~ #
\li1 …
\li1 Ìfihàn ~~ #
\periph OT Half Title Page
\mt1 Májẹ̀mú Láéláé
\periph NT Half Title Page
\mt1 Májẹ̀mú Tuntun